Sunday igboho: ''ẹ ó ríjà oba, tí ẹ bá gbìyànjú láti fọ́wọ́ kan sunday igboho'' - bbc news yorùbá

Sunday igboho: ''ẹ ó ríjà oba, tí ẹ bá gbìyànjú láti fọ́wọ́ kan sunday igboho'' - bbc news yorùbá

Play all audios:

Loading...

SUNDAY IGBOHO: ''Ẹ Ó RÍJÀ OBA, TÍ Ẹ BÁ GBÌYÀNJÚ LÁTI FỌ́WỌ́ KAN SUNDAY IGBOHO'' 21 Ẹrẹ̀nà 2021 AJIJAGBARA ILẸ YORUBA, ỌGBẸNI SUNDAY ADEYEMO TI ỌPỌ MỌ SI SUNDAY IGBOHO


TUN TI KILỌ FAWỌN TO BA N GBERO LATI MU UN. Nigba ti Igboho ṣe abẹwo si Oba ilu Oke-Iho lagbegbe Oke Ogun nipinlẹ Oyo, Oba Rafiu Osuolale Mustapha, Igboho sọ pe Alaafin Oyo, Oba Lamidi


Olayiwola Adeyemi duro gbọin-gbọin lẹyin ohun. Igboho sọ ninu fido kan to fi sori Facebook pe ''nigba tawọn ijọba Naijiria lọ ba Alaafin wi pe ko fa Sunday Igboho le wọn lọwọ, o ni


ko ṣeeṣe bẹẹ. * Kò sí Oduduwa Nation kankan ni ilẹ̀ Iwo! Kí n má gbọ́ ọ - Oluwo * Àwọn tó jí Oba Imope l'Ogun yìnbọn fún ọlọ́dẹ, Olorí ní ẹbí kábíyèsí kò ní N200M tí wọ́n ń béèrè *


'Èmi Alake yóò bi àwọn alálẹ̀ ilẹ̀ àtàwọn Ogboni ná bí mo bá tilẹ̀ máa tako Sunday Igboho ámbọ̀sìbọ́sí...' * Ẹyọ kan lára agbára tí mo ní, ni mo lò láti mú Wakili - Gani Adams *


Ǹkan pàtàkì márùn-ún tí gbogbo obìnrin tó ní ojú ara gbọ́dọ̀ mọ̀ * Ìyàtọ tàbí àfiwé wo ló wà láàrin Sunday Igboho, Nnamdi Kanu àti Asari Dokubo? Alaafin ni Sunday Igboho ti ẹ n wo yẹn, mẹwaa


ni, eleyi ti ẹ n ri yẹn to n kaakiri kii ṣe Sunday Igboho tori pe oun mọ an dele dele. Nitoripe awọn baba toun atawọn baba tiẹ jọ ṣe pọ ni. Skip Èyítí A Ń Kà Jùlọ and continue reading ÈYÍTÍ


A Ń KÀ JÙLỌ * Àwọn agbègbè tí ìwọ́de June 12 yóò ti wáyé rèé àti bó ṣe kàn ọ́ * Kí ló mú kí òkè Iya Mopo nílùú Igbeti máa ya lulẹ̀, tó tún n ṣí èèpo? Nnkan tí a mọ̀ rèé * Ìgbẹ́jọ́


Abdulrahman Bello gbọ̀nà míràn yọ n'Ilorin, ó yí òun padà lórí ẹni tó pa Hafsot Bello * Wo bí o ṣe lè dáàbò bo ara rẹ lọ́wọ́ àwọn tó ń já fóònù gbà End of Èyítí A Ń Kà Jùlọ Ti ẹ ba si


gbiyanju lati fọwọ kan Sunday Igboho, igba naa lẹ o rija ọba, Alaafin lo sọ bẹẹ. Alaafin lo kọkọ kọ lẹta si Buhari pe o to gẹẹ nipa ọrọ awọn Fulani nipinlẹ Oyo,'' Igboho lo sọ bẹẹ.


Sunday Igboho ko ṣai sọ fun Oba Mustapha pe oun ṣetan lati le awọn Fulani kuro lori ilẹ Oke-Iho ti Kabiyesi ba fẹ bẹẹ. Igboho tun sọ fun Kabiyesi nipa erongba rẹ lori bi iran Yoruba yoo ti


yapa kuro lara Naijiria. Ajijagbara Igboho ni yiyapa iran Yoruba kuro lara Naijiria ti ṣeeṣe na. Ninu ọrọ tirẹ, Oba Mustapha Adeitan Keji gbadura pe fun Igboho pe didaduro iran Yoruba yoo


ṣeeṣe.